Nípa Eto Èkọ Yií

Ile eko 360 pelu ajosepo ogbontarigi akonilede Yoruba, Ogbeni Ajakaye ni o se eto eko yi fun anfaani gbogbo awon akekoo tabi olukopa lori ikanni yi. Awon eko lorisiirisii ti a di ni ipele ipele lona ti yoo fi ye enikeni daa, Lakota, a see ni ofe fun enikeni, lati fi gbe asa ile Yoruba laruge. Asa ile wa Yoruba ko ni parun loju wa; e je ki a gbe asa wa laruge.

Èrèdií Ẹ́kọ Yií

Èrèdií ẹ́kọ yií ni lati fi imo to ye kooro mo awon akeko lori  Òwe Yorùbá, Èdè, Akanlo Èdè, Iyanrọ fẹ́rẹ́, Ìlò Èdè Nínu Sinimá, Ẹsẹ́ Ifá

Koko Èkọ́

Òwe Yorùbá

- Ìtumọ̀ òwe

- Itupalẹ òwe Yorùbá

- Ipasipayọ òwe Yorùbá  

Èdè

- Ìtumọ èdè

- Ìpínlẹ̀ èdè

- Isọwọlo èdè

Akanlo Èdè

- Ìtùmọ Akanlo èdè

- ọ̀nà ìgbà lo Akanlo èdè 

Iyanrọ fẹ́rẹ́

- Itumọ iyanrọ fẹ́rẹ́

- Ọgbọ́n iyanrọ fẹ́rẹ́

ÌLÒ ÈDÈ NÍNÚ SINIMA

- Akọtọ èdè Yorùbá

- Ede ojoojumọ

- Ede ewì

 - Èdè ajumọ lo

- Ẹka èdè

ẸṢẸ IFÁ

- Kí ni Ifá?

- Ìlò èdè inú ẹsẹ Ifá

- Lilo Ifá àti babaláwo tàbí Iyanifa nínú sinima

- Babaláwo àti Oníṣègùn